Àkójọpo Ìhìn Rere
Ìtẹ̀lẹ́ léṣeẹ́sẹ 4 awon ìséle
Ó dára fún gbogbo ebị́
Àkọ́kọ́ Ìṣàfilọ́lẹ̀ ọ̀rọ̀ -fun- ọ̀rọ̀ ìhìnrere Jesu nípa lìlò àkọsílẹ̀ ìtàn Jesu gẹgẹ bí à ṣe ri ní inú ìhìnrere ti Mátíù, Máàkù, Lùkù ati Johanu- ti on tonmọ́lẹ̀ titun si ́ọ́kan ninú awọn ọ̀rọ̀ mímọ́ jù lọ ninú ìtàn.
- Albanian
- Amharic
- Ede Larubawa
- Azerbaijani
- Bangla
- Burmese
- Cantonese
- Cebuano
- Chichewa
- Chinese
- Croatian
- Czech
- Dari
- Dutch
- Ede Gẹẹsi
- Finnish
- Faranse
- Georgian
- German
- Gujarati
- Hausa
- Heberu
- Hindi
- Hmong
- Indonesian
- Italy
- Japanese
- Kannada
- Kazakh
- Korean
- Kurdish (Kurmanji)
- Língálà
- Malayalam
- Marathi
- Nepali
- Nọọwẹjiyanu
- Odia (Oriya)
- Persian
- Polish
- Portuguese
- Punjabi
- Russian
- Serbian
- Ede Spain
- Swahili
- Tagalog
- Tajik
- Tamil
- Telugu
- Thai
- Turkish
- Turkmen
- Ukrainian
- Urdu
- Uzbek
- Vietnamese
- Ede Yoruba
awon ìséle
-
Ìhìn Rere Mátíù
Ìhìn Rere Mátíù je ihinrere ti o gba jumo ni igba aye awon kristenì àkókó. Ti a ko fún àwujo awọ̣n Kristenì bi won se bẹrẹ si n ma yapa kuro ní ... more
Ìhìn Rere Mátíù
Ìhìn Rere Mátíù je ihinrere ti o gba jumo ni igba aye awon kristenì àkókó. Ti a ko fún àwujo awọ̣n Kristenì bi won se bẹrẹ si n ma yapa kuro ní àwùjọ awon júù, Ìhìnrere Mátíù lọ jina latí ṣe afihan, gẹgẹ bi Messiah Jesu ni imuse asọtẹlẹ májẹ̀mú láíláí n toka si bi Ọlọ́run Olùgbàlà wa. Lumo Project ló ṣe àgbatéru eré yi.
-
Ìhìn Rere Máàkù
Ìhìn Rere Máàkù mú ìtàn Jesu wa si òrí amóhùn máwòrán nípa lilo àyọkà ihinrere Jesu gege bi àkọsílẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan lóye. Lumo Project l... more
Ìhìn Rere Máàkù
Ìhìn Rere Máàkù mú ìtàn Jesu wa si òrí amóhùn máwòrán nípa lilo àyọkà ihinrere Jesu gege bi àkọsílẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan lóye. Lumo Project ló ṣe àgbatéru eré yi.
-
Ìhìn Rere Lúùkù
Ju awon eyi toku lo, Ìhìn Rere Lúùkù fi ara jo ìsọ̀rí ìtàn ìgbésí ayé tàtijọ́. Lúùkù gẹ́gẹ́ bí ọ̀nitàn, ri Jesu gegẹ́ bí Olùgbàlà agbáyé tin ma sètìlẹ... more
Ìhìn Rere Lúùkù
Ju awon eyi toku lo, Ìhìn Rere Lúùkù fi ara jo ìsọ̀rí ìtàn ìgbésí ayé tàtijọ́. Lúùkù gẹ́gẹ́ bí ọ̀nitàn, ri Jesu gegẹ́ bí Olùgbàlà agbáyé tin ma sètìlẹ́yìn àwọn talákà ati aláìní. Agbáteèrù ńlá yi- ṣe afíhan àkànṣe pèpéle ati áwọn ojúlówó ìgbèríko Morocco- Awon ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn ti se lámèyítọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ojúlówó itan Jesù to dáyàtọ̀. Lumo Project ló ṣe àgbatéru eré yi.
-
Ìhìn Rere Jòhánù
Ihìn Rere Jòhánù je akọ́kọ́ ẹ̀dà aworan ti itan inu bíbélì mímọ́. Nípa lilo àyọkà ihinrere Jesu gege bi àkọsílẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan lóye, - ijì... more
Ìhìn Rere Jòhánù
Ihìn Rere Jòhánù je akọ́kọ́ ẹ̀dà aworan ti itan inu bíbélì mímọ́. Nípa lilo àyọkà ihinrere Jesu gege bi àkọsílẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan lóye, - ijìnlẹ̀aworan ti o si je ìyàlẹ́nu tan tonmọ́lẹ̀ titun si ́ọ́kan ninú awọn ọ̀rọ̀ mímọ́ jù lọ ninú ìtàn. Agbáteèrù Eré-amóhùn-máwòrán yi dara, ísèré oríìtàgé awon osere re dara, o si tò ípasẹ̀ awon iwádìí ti ẹ̀kọ́-ìsìn, ìtàn ati awalẹ̀pìtàn. Lumo Project ló ṣe àgbatéru eré yi.